
Intro:
Oni ranu lomo 'kunrin yen,
Alaseju lomo'kunrin yen
To ngberaga si baba loke
To lon naa fe dade,
Esu ti te, ani KosoRo!
Chrs:
Aye yi o le e
Baba ti se e
No more sorrow
Ani kosoro/2ce.
Verse 1:
Everything He says
He will do for you
Sohun naa lo maa se
Baba...